Jóṣúà 8:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ọ̀rọ̀ kan nínú gbogbo èyí tí Mósè pàṣẹ, tí Jósúà kò kà ní iwájú gbogbo àjọ Ísírẹ́lì, títí fi kan àwọn obìnrin àti àwọn ọmọ wọn, àti àwọn àlejò tí ń gbé ní àárin wọn.

Jóṣúà 8

Jóṣúà 8:26-35