Jóṣúà 22:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú wọn sì dùn láti gbọ́ ìròyìn náà, wọ́n sì yin Ọlọ́run. Wọn kò sì sọ̀rọ̀ mọ́ nípa lílọ bá wọn jagun láti run ilẹ̀ tí àwọn ẹ̀yà Réúbẹ́nì àti ẹ̀yà Gádì ń gbé.

Jóṣúà 22

Jóṣúà 22:30-34