Jóṣúà 22:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó sì sọ fún wọn pé, “Ẹ̀yin ti ṣe gbogbo èyí tí Mósè ìránṣẹ́ Olúwa pàṣẹ, ẹ sì ti ṣe ìgbọ́ràn sí ohun gbogbo tí mo pàṣẹ.

Jóṣúà 22

Jóṣúà 22:1-4