Jóṣúà 19:40-44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

40. Ìbò keje jáde fún ẹ̀yà Dánì, ní agbo ilé ní agbo ilé.

41. Ilẹ̀ ìní wọn nì wọ̀nyí:Sórà, Éṣtaólì, Írí-Ṣẹ́mẹ́sì,

42. Ṣáálábínì, Áíjálónì, Ítílà,

43. Élónì, Tímínà, Ékírónì,

44. Élítékè, Gíbétónì, Báálátì,

Jóṣúà 19