Jóṣúà 15:62-63 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

62. Níbíṣánì, Ìlú Iyọ̀ àti Ẹni-Gẹ́dì, ìlú mẹ́fà àti ìletò wọn.

63. Júdà kò lè lé àwọn ọmọ Jébúsì jáde, tí wọ́n ń gbé ní Jérúsálẹ́mù. Àwọn ará Jébúsì sì ń gbé pẹ̀lú àwọn ènìyàn Júdà títí dí òní.

Jóṣúà 15