Jóṣúà 15:55-60 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

55. Máónì, Kámẹ́lì, Sífì, Jútà,

56. Jésérẹ́lì, Jókídíámù, Sánóà,

57. Káínì, Gíbíátì àti Tímà: ìlú mẹ́wàá àti àwọn ìletò wọn.

58. Hálíúlì, Bẹti-Súrì, Gédórì,

59. Máárátì, Bẹti-Ánótì àti Élítékónì: ìlú mẹ́fà àti àwọn ìletò wọn.

60. Kiriati Báálì (tí í ṣe, Kiriati Jeárímù) àti Rábà ìlú méjì àti ìletò wọn.

Jóṣúà 15