Jóṣúà 15:33-36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

33. Ní ìhà ìwọ̀-oòrùn ẹsẹ̀ òkè:Ésítaólì, Sórà, Áṣínà,

34. Sánóà, Eni-Gánímù, Tápúà, Énámù,

35. Jámútì, Ádúlámù, Sókò, Ásekà,

36. Ṣááráímù, Ádítaímù àti Gédérà (tàbí Gérérótíámù), ìlú mẹ́rìnlá àti àwọn ìletò wọn.

Jóṣúà 15