Jóṣúà 15:31-34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

31. Síkílágì, Mádímánà, Sánsánà,

32. Lébáótì, Sílímù, Háínì àti Rímónì, àpapọ̀ ìlú mọ́kàndín ní ọgbọ̀n àti àwọn ìlétò wọn.

33. Ní ìhà ìwọ̀-oòrùn ẹsẹ̀ òkè:Ésítaólì, Sórà, Áṣínà,

34. Sánóà, Eni-Gánímù, Tápúà, Énámù,

Jóṣúà 15