Jóṣúà 13:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyẹn, gbogbo ilẹ̀ ọba Ógù ní Básánì, tí ó jọba ní Áṣítarótù àti Édérì, ẹni tí ó kù nínú àwọn Réfáítì ìyókù. Mósè ti ṣẹ́gun wọn, ó sì ti gba ilẹ̀ wọn.

Jóṣúà 13

Jóṣúà 13:6-22