Jóṣúà 11:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Olúwa ti pàṣẹ fún Mósè ìránṣẹ́ rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ní Mósè pàṣẹ fún Jóṣúà, Jóṣúà sì ṣe bẹ́ẹ̀. Kò fi ọ̀kankan sílẹ̀ láìṣe nínú gbogbo ohun tí Olúwa pàṣẹ fún Mósè.

Jóṣúà 11

Jóṣúà 11:7-19