Jóṣúà 10:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn ọmọ ogun sì padà sí ọ̀dọ̀ Jóṣúà ní ibùdó ogun ní Mákédà ní àlàáfíà, kò sí àwọn tí ó dábàá láti tún kọlu Ísírẹ́lì.

Jóṣúà 10

Jóṣúà 10:12-28