Jóṣúà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ilẹ̀ ẹ yín yóò fẹ̀ láti ihà u Lẹ́bánónì, àti láti odò ńlá, ti Éfúrétì—gbogbo orílẹ̀ èdè Hítì títí ó fi dé Òkun ńlá ní ìwọ̀-oòrùn.

Jóṣúà 1

Jóṣúà 1:1-7