Jóòbù 8:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ìbá mọ́, kí ó sì dúró sinṣsin:ǹjẹ́ nítòótọ́ nísinsìn yìí òun yóò tají fún ọ,òun a sì sọ ibùjókòó òdodo rẹ di púpọ̀.

Jóòbù 8

Jóòbù 8:5-11