Jóòbù 8:20-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

20. “Kíyèsí i, Ọlọ́run kì yóò ta ẹni òtítọ́ nù,bẹ́ẹ̀ ni kì yóò ran oníwà-búburú lọ́wọ́

21. títí yóò fi fi ẹ̀rín kún ọ ní ẹnu,àti ètè rẹ pẹ̀lú ìhó ayọ̀

22. ìtìjú ní a o fi bo àwọn tí ó koríra rẹ̀,àti ibùjókòó ènìyàn búburú kì yóò sí mọ́.”

Jóòbù 8