Bẹ́ẹ̀ ní Élífásì, ara Tẹ́mà, àti Bílídádì, ará Ṣúà, àti Sófárì, ará Námà lọ, wọ́n sì ṣe gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pẹ̀ṣẹ fún wọn. Olúwa sì gba àdúrà Jóòbù.