Jóòbù 41:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi kì yóò fi ẹ̀yà ara rẹ, tàbi ipárẹ, tàbí ìhámọ́ra rẹ tí ó ní ẹwà pamọ́.

Jóòbù 41

Jóòbù 41:7-16