Jóòbù 40:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wo gbogbo ìwà ìgbéraga, ènìyànkí o sì rẹ ẹ sílẹ̀, kí o sì tẹ ènìyàn búburú mọ́lẹ̀ ní ipò wọn.

Jóòbù 40

Jóòbù 40:8-22