Jóòbù 40:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fi ọlá ńlá àti ọlá ìtayọ rẹ̀ ṣe ararẹ ní ọ̀ṣọ́, tí ó sì fi ògo àti títóbi ọ̀ṣọ́ bi ara ní aṣọ.

Jóòbù 40

Jóòbù 40:1-11