Jóòbù 39:29-30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

29. Láti ibẹ̀ lọ ni ó ti ń wá oúnjẹ́kiri, ojú rẹ̀ sì ríran rí òkè réré.

30. Àwọn ọmọ rẹ̀ pẹ̀lú a máa mu ẹ̀jẹ̀,níbi tí òkú bá gbé wà, níbẹ̀ ni òun wà pẹ̀lú.”

Jóòbù 39