Jóòbù 39:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ń gbé, ó sì ń wò ní orí àpáta,lórí pàlàpálá òkúta àti ibi orí òkè.

Jóòbù 39

Jóòbù 39:23-30