Jóòbù 38:37-40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

37. Ta ni ó fi ọgbọ́n ka iye àwọ̀sánmọ̀? Ta ni ó sì mú ìgò ọ̀run dà jáde,

38. Nígbà tí erupẹ̀ di líle, àtiògúlùtú dípò?

39. “Ìwọ ha dẹ ọdẹ fún abo kìnnìún bí?Ìwọ ó sì tẹ ebi ẹgbọ̀rọ̀ kìnnìún lọ́rùn,

40. Nígbà tí wọ́n bá ń mọ́lẹ̀ nínú ihòtí wọ́n sì ba ní ibùba de ohun ọdẹ?

Jóòbù 38