Jóòbù 38:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ le mú àwọn àmì méjìlá ìràwọ̀ Másárótì jáde wá nígbà àkókò wọn?Tàbí ìwọ le ṣe amọ̀nà Béárì pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀?

Jóòbù 38

Jóòbù 38:30-40