Jóòbù 38:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Di ẹ̀gbẹ́ ara rẹ ní àmùrè bíọkùnrin nísinsin yìí, nítorí péèmi yóò béèrè lọ́wọ́ rẹ kí o sì dámi lóhùn.

Jóòbù 38

Jóòbù 38:1-5