Jóòbù 37:22-24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

22. Góòlù dídán ti inú ìhà àríwá jádewá; lọ́dọ̀ Ọlọ́run ni ọláńlá ẹ̀rùn ńlá.

23. Nipa ti Olódùmarè àwa kò le wádìí rẹ̀; ó ré kọjá ní ipá; nínúìdájọ́ àtí títí bi oun kì í ba ẹ̀tọ́ àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ òtítọ́ jẹ́.

24. Nítorí náà ènìyàn ha máa bẹ̀rùrẹ̀; òun kì í se ojú sájú ẹnikẹ́ni tí ó gbọ́n ní ayé?”

Jóòbù 37