Jóòbù 37:18-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

18. Ìwọ ha ba tẹ́ pẹpẹ ojú ọ̀run, tí ódúró sinsin, tí ó sì dàbí dígi tí ó yọ̀ dà?

19. “Kọ́ wa ní èyí tí a lè wí fún un;nítorí pé àwa kò le ílàdí ọ̀rọ̀ nítorí òkùnkùn wa.

20. A ó ha wí fún un pé, èmi fẹ́sọ̀rọ̀? Tàbí ẹnìkan lèwí pé, ìfẹ́ mi ni pé kí a gbémi mù?

Jóòbù 37