Jóòbù 34:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí pé Jóòbù wí pé, ‘Aláìlẹ́sẹ̀ ni èmi;Ọlọ́run sì ti gba ìdájọ́ mi lọ.

Jóòbù 34

Jóòbù 34:1-6