Jóòbù 34:35-37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

35. ‘Jóòbù ti fi àìmọ̀ sọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀ rẹ̀ sì ṣealáìgbọ́n.’

36. Ìfẹ́ mi ni kí a dán Jóòbù wò déòpin, nítorí ìdahùn rẹ̀ dà bí i ti ènìyàn búburú:

37. Nítorí pe ó fi ìṣọ̀tẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀; ópàtẹ́wọ́ ní àárin wa, ó sì sọọ̀rọ̀ di púpọ̀ sí Ọlọ́run.”

Jóòbù 34