Jóòbù 34:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ańbọ̀tórí fún ẹni tí kì í ṣójúṣàájú àwọn ọmọ-aládétàbí tí kò kà ọlọ́rọ̀ sí talákà lọ.Nítorí pé iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ ni gbogbo wọn í ṣe?

Jóòbù 34

Jóòbù 34:10-27