Jóòbù 34:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nígbà náà ni Élíhù dáhùn, ó sì wí pé:

2. “Ẹ̀yin ọlọ́gbọ́n ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi,kí ẹ sì fi etí sílẹ̀ sí mi ẹ̀yin tí ẹ ní ìmòye.

3. Nítorí pé etí a máa dán ọ̀rọ̀ wò,bí adùn ẹnu ti ń tọ́ oúnjẹ wò.

Jóòbù 34