Jóòbù 32:21-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

21. Lótítọ́ èmí kì yóò ṣe ojúṣàájú síẹnìkankan, bẹ́ẹ̀ ni èmí kì yóò sì ṣe ìpọ́nni fún ẹnìkan.

22. Nítorí pé èmí kò mọ̀ ọ̀rọ̀ ìpọ́nni í sọ;ní ṣíṣe bẹ́ẹ̀, Ẹlẹ́dàá mi yóò mú mi kúrò lọ́gán.

Jóòbù 32