Jóòbù 31:38-40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

38. “Bí ilẹ̀ mi bá sì ké rara lòdì sí mití a sì fi omijé kún gbogbo poro rẹ̀.

39. Bí mo bá jẹ èṣo oko mi láìsánwọ́tàbi tí mo sì mú ọkàn olúwa rẹ̀ fò lọ,

40. kí ẹ̀gún òṣùṣú kí ó hù dípòàlìkámà, àti èpò búburú dípò ọkà bárlè.”Ọ̀rọ̀ Jóòbù parí.

Jóòbù 31