Jóòbù 30:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò ha sunkún bí fún ẹni tí ówà nínú ìṣòro? Ọkàn mi kò ha bàjẹ́ fún talákà bí?

Jóòbù 30

Jóòbù 30:17-31