Jóòbù 30:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀rù ńlá bà mí; wọ́n lépa ọkànmi bí ẹ̀fúùfù, àlàáfíà mi sì kọjá lọ bí àwọ̀ sánmọ̀.

Jóòbù 30

Jóòbù 30:7-23