Jóòbù 3:23-26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

23. Kí ni a fi ìmọ́lẹ̀ fún ẹni tí ọ̀nà rẹ̀fi ara pamọ́ fúntí Ọlọ́run sì ṣọgbà yí wọn ká?

24. Nítorí pé èémí-ẹ̀dùn wà ṣáájú oúnjẹ mi;ikérora mi sì tú jáde bí omi.

25. Nítorí pé ohun náà tí mo bẹ̀rù gidigidi ni ó dé bá mi yìí,àti ohun tí mo fòyà rẹ̀ bá mi ó sì ṣubú lù mí.

26. Èmi kò wà ni ìléwu rí, bẹ́ẹ̀ ni èmi kò ní ìsinmi;bẹ́ẹ̀ ni èmi kò ni ìfàyà balẹ̀, síbẹ̀síbẹ̀ ìyọnu dé.”

Jóòbù 3