Jóòbù 29:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Pẹ̀lúpẹ̀lù, Jóòbù sì tún tẹ̀ ṣíwájú nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó sì wí pé:

2. “Áà! ìbá ṣe pé èmi wà bí ìgbà oṣù tíó kọjá, bí ọjọ́ tí Ọlọ́run pamímọ́;

Jóòbù 29