Jóòbù 27:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí kí ni ìrètí àgàbàgebè,nígbà tí Ọlọ́run bá ké ẹ̀mí rẹ̀ kúrò, nígbà tí ó sì fà á jáde?

Jóòbù 27

Jóòbù 27:1-9