Jóòbù 27:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé Olódùmárè yóò kọ lù ú,kì yóò sì dá a sí; òun ìbá yọ̀ láti sá kúrò ní ọwọ́ rẹ̀.

Jóòbù 27

Jóòbù 27:16-23