Jóòbù 26:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ṣùgbọ́n Jóòbù sì dáhùn wí pé:

2. Báwo ni ìwọ ń ṣe ìrànlọ́wọ́ ẹni tíkò ní ipá, báwo ní ìwọ ń ṣe gbà apá ẹni tí kò ní agbára?

3. Báwo ni ìwọ ń ṣe ìgbìmọ̀ ẹni tí kòní ọgbọ́n, tàbí báwo ní ìwọ sọdi ọ̀ràn ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ bí ó ti rí?

Jóòbù 26