Jóòbù 24:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúkulùkù a sì ṣa ọkà oúnjẹ ẹranrẹ̀ nínú oko, wọn a sì ká ọgbà àjàrà ènìyàn búburú.

Jóòbù 24

Jóòbù 24:5-15