Jóòbù 24:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú ìbímọ yóò gbàgbé rẹ̀, kòkòròní yóò máa fi adùn jẹun lára rẹ̀,a kì yóò rántí ènìyàn búburúmọ́; Bẹ́ẹ̀ ní a ó sì ṣẹ ìwà búburú bí ẹní ṣẹ́ igi;

Jóòbù 24

Jóòbù 24:14-23