Jóòbù 22:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àwọn olódodo rí ìparun wọn,wọ́n sì yọ̀, àwọn aláìlẹ̀ṣẹ̀ sì fi wọ́n rẹ́rìn ín ẹlẹ́yà pé,

Jóòbù 22

Jóòbù 22:16-23