Jóòbù 21:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ènìyàn búburú ní a fi pamọ́ fúnọjọ́ ìparun? A ó sì mú wọnjáde ní ọjọ́ ríru ìbínú.

Jóòbù 21

Jóòbù 21:26-34