Jóòbù 21:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìgbà mélòómélòó ní a ń pa iná ènìyànbúburú kú? Ìgbà mélòómélòó ní ìparunwọn dé bá wọn, tí Ọlọ́run sì ímáa pín ìbìnújẹ́ nínú ìbínú rẹ̀?

Jóòbù 21

Jóòbù 21:12-26