Jóòbù 20:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú tí ó ti rí i rí kì yóò sì rí i mọ́,bẹ́ẹ̀ ni ibùjókòó rẹ̀ kì yóò sì ri i mọ́.

Jóòbù 20

Jóòbù 20:1-13