Jóòbù 20:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òkùnkùn biribiri ní a ti pamọ́fún ìṣúra rẹ̀; iná ti a kò fẹ́ níyóò jó o run: yóò sì jẹ èyí tí ókù nínú àgọ́ rẹ̀ run.

Jóòbù 20

Jóòbù 20:16-29