Jóòbù 20:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun tí ó ṣíṣẹ́ fún ni yóò mú unpadà, kí yóò sì gbé e mì; gẹ́gẹ́bí ọrọ̀ tí ó ní, kì yóò sì yọ̀ nínú rẹ̀.

Jóòbù 20

Jóòbù 20:16-26