Jóòbù 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sàtánì sì dá Olúwa lóhùn wí pé, “Awọ fún awọ; àní ohun gbogbo tí ènìyàn ní, òun ni yóò fi ra ẹ̀mí rẹ̀.

Jóòbù 2

Jóòbù 2:1-7