Jóòbù 19:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹ̀yin kí ó bẹ̀rù; nítorí ìbínú níímú ìjìyà wá nípa ìdàKí ẹ̀yin kí ó lè mọ̀ pé ìdájọ́ kan ń bẹ.”

Jóòbù 19

Jóòbù 19:27-29