Jóòbù 19:23-26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

23. “Áà! Ìbáṣe pé a le kọ̀wé ọ̀rọ̀ minísinsìn yìí, ìbáṣepé a le dà á sínú ìwé!

24. Kí a fi kálàmú irin àti ti òjé kọwọ́n sínú àpáta fún láéláé.

25. Nítorí èmi mọ̀ pé olùdáùndè miń bẹ láàyè àti pe òun ni yóò dìdedúró lórí ilẹ̀ ní ìkẹyìn;

26. Àti lẹ́yìn ìgbà tí a pa àwọ̀ arami run, síbẹ̀ láìsí ẹran ara mi ni èmi ó rí Ọlọ́run,

Jóòbù 19