Jóòbù 19:19-21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

19. Gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ kòríkòsùn mikórìíra mi, àwọn olùfẹ́ mi sì kẹ̀yìndà mí.

20. Egungun mi lẹ̀ mọ́ ara mi àti mọ́ẹran ara mi, mo sì bọ́ pẹ̀lú awọ eyín mi.

21. “Ẹ ṣáànú fún mi, ẹ ṣàánú fún mi,ẹ̀yin ọ̀rẹ́ mi, nítorí ọwọ́ Ọlọ́run ti bà mí.

Jóòbù 19